Ẹ́kísódù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* ń bímọ, wọ́n sì ń pọ̀ sí i, wọ́n ń bí sí i, wọ́n sì túbọ̀ ń lágbára gidigidi, débi pé wọ́n kún ilẹ̀ náà.+ Diutarónómì 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àwọn baba ńlá rẹ àti ìdílé wọn jẹ́ àádọ́rin (70) èèyàn* nígbà tí wọ́n lọ sí Íjíbítì,+ àmọ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti mú kí o pọ̀ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run.+ Sáàmù 105:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọlọ́run mú kí àwọn èèyàn rẹ̀ pọ̀ rẹpẹtẹ;+Ó mú kí wọ́n lágbára ju àwọn ọ̀tá wọn lọ,+
7 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* ń bímọ, wọ́n sì ń pọ̀ sí i, wọ́n ń bí sí i, wọ́n sì túbọ̀ ń lágbára gidigidi, débi pé wọ́n kún ilẹ̀ náà.+
22 Àwọn baba ńlá rẹ àti ìdílé wọn jẹ́ àádọ́rin (70) èèyàn* nígbà tí wọ́n lọ sí Íjíbítì,+ àmọ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti mú kí o pọ̀ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run.+