Ẹ́kísódù 20:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “O ò gbọ́dọ̀ gbẹ́ ère kankan fún ara rẹ tàbí kí o ṣe ohun* kan tó dà bí ohunkóhun lókè ọ̀run tàbí ní ayé tàbí nínú omi nísàlẹ̀.+ Diutarónómì 4:15, 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Torí náà, ẹ ṣọ́ra gidigidi,* torí pé ẹ ò rí ẹnikẹ́ni lọ́jọ́ tí Jèhófà bá yín sọ̀rọ̀ ní Hórébù láti àárín iná náà, 16 kí ẹ má bàa hùwàkiwà nípa gbígbẹ́ ère èyíkéyìí tó jọ ohunkóhun fún ara yín, ohun tó rí bí akọ tàbí abo,+ Àìsáyà 44:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Gbogbo àwọn tó ń ṣe ère gbígbẹ́ ò já mọ́ nǹkan kan,Àwọn ohun tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí kò ní ṣàǹfààní rárá.+ Bí wọ́n tiẹ̀ jẹ́ ẹlẹ́rìí wọn, wọn* ò rí nǹkan kan, wọn ò sì mọ nǹkan kan,+Torí náà, ojú máa ti àwọn tó ṣe wọ́n.+
4 “O ò gbọ́dọ̀ gbẹ́ ère kankan fún ara rẹ tàbí kí o ṣe ohun* kan tó dà bí ohunkóhun lókè ọ̀run tàbí ní ayé tàbí nínú omi nísàlẹ̀.+
15 “Torí náà, ẹ ṣọ́ra gidigidi,* torí pé ẹ ò rí ẹnikẹ́ni lọ́jọ́ tí Jèhófà bá yín sọ̀rọ̀ ní Hórébù láti àárín iná náà, 16 kí ẹ má bàa hùwàkiwà nípa gbígbẹ́ ère èyíkéyìí tó jọ ohunkóhun fún ara yín, ohun tó rí bí akọ tàbí abo,+
9 Gbogbo àwọn tó ń ṣe ère gbígbẹ́ ò já mọ́ nǹkan kan,Àwọn ohun tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí kò ní ṣàǹfààní rárá.+ Bí wọ́n tiẹ̀ jẹ́ ẹlẹ́rìí wọn, wọn* ò rí nǹkan kan, wọn ò sì mọ nǹkan kan,+Torí náà, ojú máa ti àwọn tó ṣe wọ́n.+