Sáàmù 115:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn òrìṣà wọn jẹ́ fàdákà àti wúrà,Iṣẹ́ ọwọ́ èèyàn.+ 5 Wọ́n ní ẹnu, àmọ́ wọn ò lè sọ̀rọ̀;+Wọ́n ní ojú, àmọ́ wọn ò lè ríran;
4 Àwọn òrìṣà wọn jẹ́ fàdákà àti wúrà,Iṣẹ́ ọwọ́ èèyàn.+ 5 Wọ́n ní ẹnu, àmọ́ wọn ò lè sọ̀rọ̀;+Wọ́n ní ojú, àmọ́ wọn ò lè ríran;