-
Diutarónómì 28:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “Àmọ́ tí o ò bá pa gbogbo àṣẹ àti òfin Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́, èyí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí, láti fi hàn pé ò ń fetí sí ohùn rẹ̀, gbogbo ègún yìí máa wá sórí rẹ, ó sì máa bá ọ:+
-
-
Gálátíà 3:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Gbogbo àwọn tó gbára lé àwọn iṣẹ́ òfin wà lábẹ́ ègún, nítorí ó wà lákọsílẹ̀ pé: “Ègún ni fún gbogbo ẹni tí kò bá dúró nínú gbogbo ohun tó wà lákọsílẹ̀ nínú àkájọ ìwé Òfin láti pa wọ́n mọ́.”+
-