ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 27:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 “‘Ègún ni fún ẹni tí kò bá pa àwọn ọ̀rọ̀ inú Òfin yìí mọ́ láti fi hàn pé ó fara mọ́ wọn.’+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)

  • Ìṣe 15:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Kí ló wá dé tí ẹ fi ń dán Ọlọ́run wò báyìí, tí ẹ̀ ń gbé àjàgà+ tí àwọn baba ńlá wa tàbí àwa fúnra wa kò lè rù kọ́ ọrùn àwọn ọmọ ẹ̀yìn?+

  • Jémíìsì 2:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Torí tí ẹnikẹ́ni bá ń pa gbogbo Òfin mọ́ àmọ́ tó ṣi ẹsẹ̀ gbé nínú ọ̀kan, ó ti rú gbogbo òfin.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́