-
Diutarónómì 11:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 màá mú kí òjò rọ̀ sórí ilẹ̀ yín ní àkókò rẹ̀, òjò ìgbà ìkórè àti ti ìgbà ìrúwé, ẹ sì máa kó ọkà yín jọ àti wáìnì tuntun yín àti òróró yín.+
-