Àìsáyà 5:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí pé òṣùwọ̀n báàtì* kan ṣoṣo ni éékà ilẹ̀ mẹ́wàá* tí wọ́n gbin àjàrà sí máa mú jáde,Eéfà* kan ṣoṣo sì ni irúgbìn tó jẹ́ òṣùwọ̀n hómérì* kan máa mú jáde.+ Hágáì 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ ti fún irúgbìn tó pọ̀, àmọ́ irè oko díẹ̀ ni ẹ kó.+ Ẹ̀ ń jẹun, àmọ́ ẹ ò yó. Ẹ̀ ń mu, àmọ́ kò tẹ́ yín lọ́rùn. Ẹ̀ ń wọṣọ, àmọ́ ara ẹnì kankan yín ò móoru. Inú ajádìí àpò ni ẹni tí wọ́n gbà síṣẹ́ ń kó owó iṣẹ́ rẹ̀ sí.’”
10 Torí pé òṣùwọ̀n báàtì* kan ṣoṣo ni éékà ilẹ̀ mẹ́wàá* tí wọ́n gbin àjàrà sí máa mú jáde,Eéfà* kan ṣoṣo sì ni irúgbìn tó jẹ́ òṣùwọ̀n hómérì* kan máa mú jáde.+
6 Ẹ ti fún irúgbìn tó pọ̀, àmọ́ irè oko díẹ̀ ni ẹ kó.+ Ẹ̀ ń jẹun, àmọ́ ẹ ò yó. Ẹ̀ ń mu, àmọ́ kò tẹ́ yín lọ́rùn. Ẹ̀ ń wọṣọ, àmọ́ ara ẹnì kankan yín ò móoru. Inú ajádìí àpò ni ẹni tí wọ́n gbà síṣẹ́ ń kó owó iṣẹ́ rẹ̀ sí.’”