Nọ́ńbà 32:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Mósè fún àwọn ọmọ Gádì, àwọn ọmọ Rúbẹ́nì+ àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè+ ọmọ Jósẹ́fù ní ilẹ̀ tí Síhónì+ ọba àwọn Ámórì ti ń jọba àti ilẹ̀ ti Ógù+ ọba Báṣánì ti ń jọba, ilẹ̀ tó wà láwọn ìlú rẹ̀ ní àwọn agbègbè yẹn àti àwọn ìlú tó yí ilẹ̀ náà ká. Sáàmù 135:10-12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ó pa ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè+ run,Ó sì pa àwọn ọba alágbára+11 —Síhónì ọba àwọn Ámórì,+Ógù ọba Báṣánì+Àti gbogbo àwọn ìjọba Kénáánì. 12 Ó fi ilẹ̀ wọn ṣe ogún,Ó fi ṣe ogún fún Ísírẹ́lì, àwọn èèyàn rẹ̀.+
33 Mósè fún àwọn ọmọ Gádì, àwọn ọmọ Rúbẹ́nì+ àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè+ ọmọ Jósẹ́fù ní ilẹ̀ tí Síhónì+ ọba àwọn Ámórì ti ń jọba àti ilẹ̀ ti Ógù+ ọba Báṣánì ti ń jọba, ilẹ̀ tó wà láwọn ìlú rẹ̀ ní àwọn agbègbè yẹn àti àwọn ìlú tó yí ilẹ̀ náà ká.
10 Ó pa ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè+ run,Ó sì pa àwọn ọba alágbára+11 —Síhónì ọba àwọn Ámórì,+Ógù ọba Báṣánì+Àti gbogbo àwọn ìjọba Kénáánì. 12 Ó fi ilẹ̀ wọn ṣe ogún,Ó fi ṣe ogún fún Ísírẹ́lì, àwọn èèyàn rẹ̀.+