Jeremáyà 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wò ó! Ọ̀tá yóò wá bí òjò tó ṣú,Àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀ á sì wá bí ìjì.+ Àwọn ẹṣin rẹ̀ yára ju ẹyẹ idì lọ.+ A gbé, torí pé a ti di ahoro! Hósíà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Fi ìwo sí ẹnu rẹ!+ Ọ̀tá kan ń bọ̀ bí ẹyẹ idì sí ilé Jèhófà,+Torí pé wọ́n ti da májẹ̀mú mi,+ wọ́n sì ti rú òfin mi.+
13 Wò ó! Ọ̀tá yóò wá bí òjò tó ṣú,Àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀ á sì wá bí ìjì.+ Àwọn ẹṣin rẹ̀ yára ju ẹyẹ idì lọ.+ A gbé, torí pé a ti di ahoro!
8 “Fi ìwo sí ẹnu rẹ!+ Ọ̀tá kan ń bọ̀ bí ẹyẹ idì sí ilé Jèhófà,+Torí pé wọ́n ti da májẹ̀mú mi,+ wọ́n sì ti rú òfin mi.+