Jóṣúà 7:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Jóṣúà sọ pé: “Kí ló dé tí o fa àjálù* bá wa?+ Jèhófà máa mú àjálù bá ọ lónìí.” Ni gbogbo Ísírẹ́lì bá sọ ọ́ lókùúta,+ lẹ́yìn náà, wọ́n dáná sun wọ́n.+ Bí wọ́n ṣe sọ gbogbo wọn lókùúta nìyẹn.
25 Jóṣúà sọ pé: “Kí ló dé tí o fa àjálù* bá wa?+ Jèhófà máa mú àjálù bá ọ lónìí.” Ni gbogbo Ísírẹ́lì bá sọ ọ́ lókùúta,+ lẹ́yìn náà, wọ́n dáná sun wọ́n.+ Bí wọ́n ṣe sọ gbogbo wọn lókùúta nìyẹn.