Jóṣúà 6:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àmọ́ ẹ yẹra fún ohun tí a máa pa run,+ kí ọkàn yín má bàa fà sí i, kí ẹ sì mú un,+ tí ẹ ó fi mú àjálù* bá ibùdó Ísírẹ́lì, tí ẹ ó sì sọ ọ́ di ohun tí a máa pa run.+ 1 Kíróníkà 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọmọ* Kámì ni Ákárì,* ẹni tó mú àjálù* bá Ísírẹ́lì+ nígbà tó hùwà àìṣòótọ́ torí ó mú ohun tí wọ́n fẹ́ pa run.+
18 Àmọ́ ẹ yẹra fún ohun tí a máa pa run,+ kí ọkàn yín má bàa fà sí i, kí ẹ sì mú un,+ tí ẹ ó fi mú àjálù* bá ibùdó Ísírẹ́lì, tí ẹ ó sì sọ ọ́ di ohun tí a máa pa run.+
7 Ọmọ* Kámì ni Ákárì,* ẹni tó mú àjálù* bá Ísírẹ́lì+ nígbà tó hùwà àìṣòótọ́ torí ó mú ohun tí wọ́n fẹ́ pa run.+