-
Nọ́ńbà 31:22, 23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 ‘Wúrà, fàdákà, bàbà, irin, tánganran àti òjé nìkan, 23 gbogbo nǹkan tí kò lè tètè jóná, ni kí ẹ kó sínú iná, yóò sì mọ́. Àmọ́ kí ẹ tún fi omi ìwẹ̀mọ́ wẹ̀ ẹ́ mọ́.+ Kí ẹ kó gbogbo nǹkan tó lè tètè jóná sínú omi.
-