Jóṣúà 6:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àmọ́ gbogbo fàdákà, wúrà, àwọn ohun tí wọ́n fi bàbà àti irin ṣe jẹ́ ohun mímọ́ fún Jèhófà.+ Ibi ìṣúra Jèhófà ni kí ẹ kó o lọ.”+
19 Àmọ́ gbogbo fàdákà, wúrà, àwọn ohun tí wọ́n fi bàbà àti irin ṣe jẹ́ ohun mímọ́ fún Jèhófà.+ Ibi ìṣúra Jèhófà ni kí ẹ kó o lọ.”+