-
Jóṣúà 5:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣì dúró sí Gílígálì tí wọ́n pàgọ́ sí, wọ́n ṣe Ìrékọjá ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹrìnlá oṣù,+ ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Jẹ́ríkò.
-
-
Jóṣúà 10:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Lẹ́yìn náà, Jóṣúà àti gbogbo Ísírẹ́lì pa dà sí ibùdó ní Gílígálì.+
-