Jóṣúà 10:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Jóṣúà gba Mákédà+ ní ọjọ́ yẹn, ó sì fi idà pa á run. Ó pa ọba rẹ̀ àti gbogbo àwọn* tó ń gbé ibẹ̀ run, kò ṣẹ́ ẹnì kankan kù.+ Ohun tó ṣe sí ọba Jẹ́ríkò gẹ́lẹ́ ló ṣe sí ọba Mákédà.+
28 Jóṣúà gba Mákédà+ ní ọjọ́ yẹn, ó sì fi idà pa á run. Ó pa ọba rẹ̀ àti gbogbo àwọn* tó ń gbé ibẹ̀ run, kò ṣẹ́ ẹnì kankan kù.+ Ohun tó ṣe sí ọba Jẹ́ríkò gẹ́lẹ́ ló ṣe sí ọba Mákédà.+