ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 10:3-5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Adoni-sédékì ọba Jerúsálẹ́mù wá ránṣẹ́ sí Hóhámù ọba Hébúrónì,+ Pírámù ọba Jámútì, Jáfíà ọba Lákíṣì àti Débírì ọba Ẹ́gílónì+ pé: 4 “Ẹ wá ràn mí lọ́wọ́, ká lè jọ gbógun ja Gíbíónì, torí ó ti bá Jóṣúà àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe àdéhùn àlàáfíà.”+ 5 Ni àwọn ọba Ámórì+ márààrún bá kóra jọ pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun wọn, ìyẹn ọba Jerúsálẹ́mù, ọba Hébúrónì, ọba Jámútì, ọba Lákíṣì àti ọba Ẹ́gílónì, wọ́n sì lọ pàgọ́ ti Gíbíónì láti bá a jà.

  • Jóṣúà 12:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ìwọ̀nyí ni àwọn ọba ilẹ̀ tí Jóṣúà àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣẹ́gun lápá ìwọ̀ oòrùn Jọ́dánì, láti Baali-gádì,+ ní Àfonífojì Lẹ́bánónì+ títí dé Òkè Hálákì,+ tó lọ dé Séírì,+ tí Jóṣúà wá fún àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì ní ilẹ̀ àwọn ọba náà pé kó di tiwọn, bí ìpín wọn,+

  • Jóṣúà 12:10-12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 ọba Jerúsálẹ́mù, ọ̀kan; ọba Hébúrónì,+ ọ̀kan;

      11 ọba Jámútì, ọ̀kan; ọba Lákíṣì, ọ̀kan;

      12 ọba Ẹ́gílónì, ọ̀kan; ọba Gésérì,+ ọ̀kan;

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́