ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 21:22, 23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 “Tí ẹnì kan bá dẹ́ṣẹ̀, tó sì jẹ́ pé ikú ni ìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, tí ẹ ti pa á,+ tí ẹ sì ti gbé e kọ́ sórí òpó igi,+ 23 ẹ má fi òkú rẹ̀ sílẹ̀ lórí òpó igi náà di ọjọ́ kejì.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, kí ẹ rí i pé ẹ sin ín lọ́jọ́ yẹn, torí ẹni ègún ni ẹni tí a gbé kọ́ jẹ́ lójú Ọlọ́run,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ sọ ilẹ̀ yín di aláìmọ́, èyí tí Jèhófà Ọlọ́run yín fẹ́ fún yín pé kí ẹ jogún.+

  • Jóṣúà 8:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Ó gbé ọba Áì kọ́ sórí òpó igi* títí di ìrọ̀lẹ́, nígbà tí oòrùn sì ti fẹ́ wọ̀, Jóṣúà pàṣẹ pé kí wọ́n sọ òkú rẹ̀ kalẹ̀ látorí òpó igi.+ Wọ́n sì jù ú síbi àbáwọlé ẹnubodè ìlú náà, wọ́n kó òkúta lé e lórí pelemọ, ó sì wà níbẹ̀ títí dòní.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́