Diutarónómì 31:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Mósè wá pe Jóṣúà, ó sì sọ fún un níṣojú gbogbo Ísírẹ́lì pé: “Jẹ́ onígboyà àti alágbára,+ torí ìwọ lo máa mú àwọn èèyàn yìí wọ ilẹ̀ tí Jèhófà búra fún àwọn baba ńlá wọn pé òun máa fún wọn, wàá sì fún wọn kí wọ́n lè jogún rẹ̀.+ Jóṣúà 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jẹ́ onígboyà àti alágbára,+ torí ìwọ lo máa mú kí àwọn èèyàn yìí jogún ilẹ̀ tí mo búra fún àwọn baba ńlá wọn pé màá fún wọn.+ Jóṣúà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ṣebí mo ti pàṣẹ fún ọ? Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, má sì jáyà, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ.”+
7 Mósè wá pe Jóṣúà, ó sì sọ fún un níṣojú gbogbo Ísírẹ́lì pé: “Jẹ́ onígboyà àti alágbára,+ torí ìwọ lo máa mú àwọn èèyàn yìí wọ ilẹ̀ tí Jèhófà búra fún àwọn baba ńlá wọn pé òun máa fún wọn, wàá sì fún wọn kí wọ́n lè jogún rẹ̀.+
6 Jẹ́ onígboyà àti alágbára,+ torí ìwọ lo máa mú kí àwọn èèyàn yìí jogún ilẹ̀ tí mo búra fún àwọn baba ńlá wọn pé màá fún wọn.+
9 Ṣebí mo ti pàṣẹ fún ọ? Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, má sì jáyà, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ.”+