Àwọn Onídàájọ́ 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nígbà náà, Júdà gba Gásà+ àti agbègbè rẹ̀, Áṣíkẹ́lónì+ àti agbègbè rẹ̀ pẹ̀lú Ẹ́kírónì+ àti agbègbè rẹ̀.
18 Nígbà náà, Júdà gba Gásà+ àti agbègbè rẹ̀, Áṣíkẹ́lónì+ àti agbègbè rẹ̀ pẹ̀lú Ẹ́kírónì+ àti agbègbè rẹ̀.