Nehemáyà 11:25, 26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ní ti àwọn ibi tí wọ́n tẹ̀ dó sí pẹ̀lú àwọn pápá wọn, àwọn kan lára àwọn èèyàn Júdà ń gbé ní Kiriati-ábà+ àti àwọn àrọko rẹ̀,* ní Díbónì àti àwọn àrọko rẹ̀, ní Jekabúsélì+ àti àwọn ìgbèríko rẹ̀, 26 ní Jéṣúà, ní Móládà,+ ní Bẹti-pélétì,+
25 Ní ti àwọn ibi tí wọ́n tẹ̀ dó sí pẹ̀lú àwọn pápá wọn, àwọn kan lára àwọn èèyàn Júdà ń gbé ní Kiriati-ábà+ àti àwọn àrọko rẹ̀,* ní Díbónì àti àwọn àrọko rẹ̀, ní Jekabúsélì+ àti àwọn ìgbèríko rẹ̀, 26 ní Jéṣúà, ní Móládà,+ ní Bẹti-pélétì,+