Jẹ́nẹ́sísì 23:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Sérà kú sí Kiriati-ábà,+ ìyẹn Hébúrónì,+ ní ilẹ̀ Kénáánì.+ Ábúráhámù wá bẹ̀rẹ̀ sí í ṣọ̀fọ̀, ó sì ń sunkún nítorí Sérà. Jóṣúà 14:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Kiriati-ábà+ ni Hébúrónì ń jẹ́ tẹ́lẹ̀ (Ábà jẹ́ ẹni ńlá láàárín àwọn Ánákímù). Ogun sì dáwọ́ dúró ní ilẹ̀ náà.+
2 Sérà kú sí Kiriati-ábà,+ ìyẹn Hébúrónì,+ ní ilẹ̀ Kénáánì.+ Ábúráhámù wá bẹ̀rẹ̀ sí í ṣọ̀fọ̀, ó sì ń sunkún nítorí Sérà.
15 Kiriati-ábà+ ni Hébúrónì ń jẹ́ tẹ́lẹ̀ (Ábà jẹ́ ẹni ńlá láàárín àwọn Ánákímù). Ogun sì dáwọ́ dúró ní ilẹ̀ náà.+