Àwọn Onídàájọ́ 1:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Mánásè ò gba Bẹti-ṣéánì àti àwọn àrọko rẹ̀,* Táánákì+ àti àwọn àrọko rẹ̀, àwọn tó ń gbé Dórì àti àwọn àrọko rẹ̀, àwọn tó ń gbé Íbíléámù àti àwọn àrọko+ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn tó ń gbé Mẹ́gídò àti àwọn àrọko rẹ̀. Àwọn ọmọ Kénáánì ṣì ń gbé ní ilẹ̀ yìí.
27 Mánásè ò gba Bẹti-ṣéánì àti àwọn àrọko rẹ̀,* Táánákì+ àti àwọn àrọko rẹ̀, àwọn tó ń gbé Dórì àti àwọn àrọko rẹ̀, àwọn tó ń gbé Íbíléámù àti àwọn àrọko+ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn tó ń gbé Mẹ́gídò àti àwọn àrọko rẹ̀. Àwọn ọmọ Kénáánì ṣì ń gbé ní ilẹ̀ yìí.