ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 4:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Nígbà tí àwọn àlùfáà tó gbé àpótí+ májẹ̀mú Jèhófà jáde ní àárín Jọ́dánì, tí àtẹ́lẹsẹ̀ àwọn àlùfáà náà sì kan orí ilẹ̀, omi odò Jọ́dánì tún bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàn, ó sì kún bo bèbè rẹ̀+ bó ṣe wà tẹ́lẹ̀.

  • 1 Kíróníkà 12:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àwọn ọkùnrin yìí ló sọdá Jọ́dánì ní oṣù kìíní nígbà tí ó kún bo bèbè rẹ̀, wọ́n sì lé gbogbo àwọn tó ń gbé ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ lọ sápá ìlà oòrùn àti sápá ìwọ̀ oòrùn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́