Jóṣúà 15:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé. Jóṣúà 15:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ní Ṣẹ́fẹ́là,+ àwọn ìlú náà ni: Éṣítáólì, Sórà,+ Áṣínà, Àwọn Onídàájọ́ 13:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Láàárín àkókò yìí, ọkùnrin ará Sórà+ kan wà, ó wá látinú ìdílé àwọn ọmọ Dánì,+ Mánóà+ ni orúkọ rẹ̀. Ìyàwó rẹ̀ yàgàn, kò sì bímọ kankan.+
2 Láàárín àkókò yìí, ọkùnrin ará Sórà+ kan wà, ó wá látinú ìdílé àwọn ọmọ Dánì,+ Mánóà+ ni orúkọ rẹ̀. Ìyàwó rẹ̀ yàgàn, kò sì bímọ kankan.+