Jóṣúà 19:40, 41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Kèké keje+ mú ẹ̀yà Dánì+ ní ìdílé-ìdílé. 41 Ààlà ogún wọn sì ni Sórà,+ Éṣítáólì, Iri-ṣéméṣì, Àwọn Onídàájọ́ 16:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Lẹ́yìn náà, àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo ìdílé bàbá rẹ̀ wá gbé e kúrò níbẹ̀. Wọ́n sì gbé e gòkè wá, wọ́n sin ín sáàárín Sórà+ àti Éṣítáólì, ní ibojì Mánóà+ bàbá rẹ̀. Ogún (20) ọdún+ ló fi ṣe onídàájọ́ ní Ísírẹ́lì.
31 Lẹ́yìn náà, àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo ìdílé bàbá rẹ̀ wá gbé e kúrò níbẹ̀. Wọ́n sì gbé e gòkè wá, wọ́n sin ín sáàárín Sórà+ àti Éṣítáólì, ní ibojì Mánóà+ bàbá rẹ̀. Ogún (20) ọdún+ ló fi ṣe onídàájọ́ ní Ísírẹ́lì.