-
Jóṣúà 21:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe fi kèké pín àwọn ìlú yìí àtàwọn ibi ìjẹko wọn fún àwọn ọmọ Léfì nìyẹn, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+
-
-
1 Kíróníkà 6:77, 78Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
77 Látinú ẹ̀yà Sébúlúnì,+ wọ́n fún àwọn ọmọ Mérárì tó ṣẹ́ kù ní Rímónò pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Tábórì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀; 78 láti ara ilẹ̀ ẹ̀yà Rúbẹ́nì tó wà ní agbègbè ilẹ̀ Jọ́dánì ní Jẹ́ríkò títí dé apá ìlà oòrùn Jọ́dánì, wọ́n fún wọn ní Bésérì tó wà ní aginjù pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Jáhásì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀,
-