Nọ́ńbà 35:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Kí ẹ yan àwọn ìlú tó rọ̀ yín lọ́rùn láti fi ṣe ìlú ààbò, tí ẹni* tó bá ṣèèṣì pa èèyàn* máa sá lọ.+ Nọ́ńbà 35:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ìlú mẹ́fà yìí máa jẹ́ ìlú ààbò fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àjèjì+ àtàwọn tí wọ́n jọ ń gbé, ibẹ̀ ni ẹnikẹ́ni tó bá ṣèèṣì pa èèyàn*+ máa sá wọ̀.
11 Kí ẹ yan àwọn ìlú tó rọ̀ yín lọ́rùn láti fi ṣe ìlú ààbò, tí ẹni* tó bá ṣèèṣì pa èèyàn* máa sá lọ.+
15 Ìlú mẹ́fà yìí máa jẹ́ ìlú ààbò fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àjèjì+ àtàwọn tí wọ́n jọ ń gbé, ibẹ̀ ni ẹnikẹ́ni tó bá ṣèèṣì pa èèyàn*+ máa sá wọ̀.