1 Kíróníkà 6:57 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Àwọn ọmọ Áárónì ni wọ́n fún ní àwọn ìlú* ààbò,+ Hébúrónì+ àti Líbínà+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Játírì+ àti Éṣítémóà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko rẹ̀,+ 1 Kíróníkà 6:60 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 60 láti inú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì, Gébà+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Álémétì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Ánátótì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀. Gbogbo ìlú tí wọ́n fún ìdílé wọn jẹ́ mẹ́tàlá (13).+
57 Àwọn ọmọ Áárónì ni wọ́n fún ní àwọn ìlú* ààbò,+ Hébúrónì+ àti Líbínà+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Játírì+ àti Éṣítémóà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko rẹ̀,+
60 láti inú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì, Gébà+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Álémétì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Ánátótì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀. Gbogbo ìlú tí wọ́n fún ìdílé wọn jẹ́ mẹ́tàlá (13).+