Jóṣúà 18:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nígbà náà, gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé jọ sí Ṣílò,+ wọ́n sì to àgọ́ ìpàdé síbẹ̀,+ torí wọ́n ti ṣẹ́gun ilẹ̀ náà.+ Jóṣúà 19:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Èyí ni àwọn ogún tí àlùfáà Élíásárì, Jóṣúà ọmọ Núnì àtàwọn olórí agbo ilé bàbá nínú ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi kèké pín+ ní Ṣílò+ níwájú Jèhófà, ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.+ Bí wọ́n ṣe pín àwọn ilẹ̀ náà tán nìyẹn.
18 Nígbà náà, gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé jọ sí Ṣílò,+ wọ́n sì to àgọ́ ìpàdé síbẹ̀,+ torí wọ́n ti ṣẹ́gun ilẹ̀ náà.+
51 Èyí ni àwọn ogún tí àlùfáà Élíásárì, Jóṣúà ọmọ Núnì àtàwọn olórí agbo ilé bàbá nínú ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi kèké pín+ ní Ṣílò+ níwájú Jèhófà, ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.+ Bí wọ́n ṣe pín àwọn ilẹ̀ náà tán nìyẹn.