2 Sámúẹ́lì 22:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Ìdí nìyẹn tí màá fi dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà, láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+Màá sì fi orin yin*+ orúkọ rẹ: Sáàmù 7:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Màá yin Jèhófà nítorí òdodo rẹ̀,+Màá sì fi orin yin* orúkọ Jèhófà+ Ẹni Gíga Jù Lọ.+
50 Ìdí nìyẹn tí màá fi dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà, láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+Màá sì fi orin yin*+ orúkọ rẹ: