Sáàmù 35:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nígbà náà, ahọ́n mi yóò máa ròyìn* òdodo rẹ,+Yóò sì máa yìn ọ́ láti àárọ̀ ṣúlẹ̀.+