Sáàmù 51:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Gbà mí lọ́wọ́ ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀,+ ìwọ Ọlọ́run, Ọlọ́run ìgbàlà mi,+Kí ahọ́n mi lè máa fi ìdùnnú kéde òdodo rẹ.+
14 Gbà mí lọ́wọ́ ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀,+ ìwọ Ọlọ́run, Ọlọ́run ìgbàlà mi,+Kí ahọ́n mi lè máa fi ìdùnnú kéde òdodo rẹ.+