ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 28:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 “Àmọ́ tí o ò bá pa gbogbo àṣẹ àti òfin Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́, èyí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí, láti fi hàn pé ò ń fetí sí ohùn rẹ̀, gbogbo ègún yìí máa wá sórí rẹ, ó sì máa bá ọ:+

  • Diutarónómì 28:48
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 48 Jèhófà máa mú kí àwọn ọ̀tá rẹ dìde sí ọ, o sì máa sìn+ wọ́n tòun ti ebi+ àti òùngbẹ, láìsí aṣọ gidi lọ́rùn rẹ àti láìní ohunkóhun. Ó máa fi àjàgà irin sí ọ lọ́rùn títí ó fi máa pa ọ́ run.

  • Àwọn Onídàájọ́ 2:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Jèhófà wá bínú gidigidi sí Ísírẹ́lì, torí náà, ó fi wọ́n lé àwọn tó ń kóni lẹ́rù lọ́wọ́.+ Ó fi wọ́n lé ọwọ́ àwọn ọ̀tá tó yí wọn ká,+ apá wọn ò sì ká àwọn ọ̀tá wọn mọ́.+

  • Nehemáyà 9:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 “Àmọ́, nígbà tí ara bá ti tù wọ́n, wọ́n á tún ṣe ohun tó burú níwájú rẹ,+ wàá sì fi wọ́n sílẹ̀ sọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wọn, wọ́n á sì jọba lé wọn lórí.*+ Lẹ́yìn náà, wọ́n á pa dà, wọ́n á sì ké pè ọ́ pé kí o ran àwọn lọ́wọ́,+ wàá gbọ́ láti ọ̀run, léraléra lo sì ń gbà wọ́n nítorí àánú ńlá rẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́