Jẹ́nẹ́sísì 49:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ní ti ìwọ Júdà,+ àwọn arákùnrin rẹ yóò yìn ọ́.+ Ọwọ́ rẹ yóò wà ní ọrùn àwọn ọ̀tá rẹ.+ Àwọn ọmọ bàbá rẹ yóò tẹrí ba fún ọ.+ Diutarónómì 33:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó sì súre fún Júdà+ pé: “Ìwọ Jèhófà, gbọ́ ohùn Júdà,+Kí o sì mú un pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn rẹ̀. Ọwọ́ rẹ̀ ti gbèjà* ohun tó jẹ́ tirẹ̀,Ràn án lọ́wọ́ kó lè borí àwọn ọ̀tá rẹ̀.”+ 1 Kíróníkà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Òótọ́ ni pé Júdà+ ta yọ àwọn arákùnrin rẹ̀, ọ̀dọ̀ rẹ̀ sì ni ẹni tó máa jẹ́ aṣáájú+ ti wá, síbẹ̀ Jósẹ́fù ló ni ẹ̀tọ́ àkọ́bí.
8 “Ní ti ìwọ Júdà,+ àwọn arákùnrin rẹ yóò yìn ọ́.+ Ọwọ́ rẹ yóò wà ní ọrùn àwọn ọ̀tá rẹ.+ Àwọn ọmọ bàbá rẹ yóò tẹrí ba fún ọ.+
7 Ó sì súre fún Júdà+ pé: “Ìwọ Jèhófà, gbọ́ ohùn Júdà,+Kí o sì mú un pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn rẹ̀. Ọwọ́ rẹ̀ ti gbèjà* ohun tó jẹ́ tirẹ̀,Ràn án lọ́wọ́ kó lè borí àwọn ọ̀tá rẹ̀.”+
2 Òótọ́ ni pé Júdà+ ta yọ àwọn arákùnrin rẹ̀, ọ̀dọ̀ rẹ̀ sì ni ẹni tó máa jẹ́ aṣáájú+ ti wá, síbẹ̀ Jósẹ́fù ló ni ẹ̀tọ́ àkọ́bí.