Àwọn Onídàájọ́ 6:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Tí Ísírẹ́lì bá fún irúgbìn, àwọn ọmọ Mídíánì, Ámálékì+ àti àwọn Ará Ìlà Oòrùn+ máa wá gbógun jà wọ́n. Àwọn Onídàájọ́ 7:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Mídíánì, Ámálékì àti gbogbo àwọn Ará Ìlà Oòrùn+ kóra jọ sí pẹ̀tẹ́lẹ̀ náà, wọ́n pọ̀ bí eéṣú, àwọn ràkúnmí wọn kò sì níye,+ wọ́n pọ̀ bí iyanrìn etí òkun.
3 Tí Ísírẹ́lì bá fún irúgbìn, àwọn ọmọ Mídíánì, Ámálékì+ àti àwọn Ará Ìlà Oòrùn+ máa wá gbógun jà wọ́n.
12 Mídíánì, Ámálékì àti gbogbo àwọn Ará Ìlà Oòrùn+ kóra jọ sí pẹ̀tẹ́lẹ̀ náà, wọ́n pọ̀ bí eéṣú, àwọn ràkúnmí wọn kò sì níye,+ wọ́n pọ̀ bí iyanrìn etí òkun.