Àwọn Onídàájọ́ 6:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Gbogbo àwọn ọmọ Mídíánì,+ Ámálékì+ àti àwọn Ará Ìlà Oòrùn wá da àwọn ọmọ ogun wọn pọ̀;+ wọ́n sọdá* sí Àfonífojì* Jésírẹ́lì, wọ́n sì pàgọ́.
33 Gbogbo àwọn ọmọ Mídíánì,+ Ámálékì+ àti àwọn Ará Ìlà Oòrùn wá da àwọn ọmọ ogun wọn pọ̀;+ wọ́n sọdá* sí Àfonífojì* Jésírẹ́lì, wọ́n sì pàgọ́.