-
Àwọn Onídàájọ́ 2:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Àmọ́ tí onídàájọ́ náà bá kú, wọ́n á tún bẹ̀rẹ̀ sí í hùwà ìbàjẹ́ tó ju ti àwọn bàbá wọn lọ ní ti pé, wọ́n á máa tẹ̀ lé àwọn ọlọ́run míì, wọ́n á máa sìn wọ́n, wọ́n á sì máa forí balẹ̀ fún wọn.+ Wọn ò fi ìwà wọn àti agídí wọn sílẹ̀.
-