Nọ́ńbà 20:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ní oṣù kìíní, gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dé aginjù Síínì, àwọn èèyàn náà sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ní Kádéṣì.+ Ibẹ̀ ni Míríámù+ kú sí, ibẹ̀ sì ni wọ́n sin ín sí.
20 Ní oṣù kìíní, gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dé aginjù Síínì, àwọn èèyàn náà sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ní Kádéṣì.+ Ibẹ̀ ni Míríámù+ kú sí, ibẹ̀ sì ni wọ́n sin ín sí.