Àwọn Onídàájọ́ 13:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Rí i pé o ò mu wáìnì tàbí ohunkóhun tó ní ọtí,+ má sì jẹ ohun àìmọ́ kankan.+