ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 6:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Tí ọkùnrin tàbí obìnrin kan bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ pàtàkì pé òun fẹ́ di Násírì*+ fún Jèhófà, 3 kó yẹra fún wáìnì àti àwọn ohun mímu míì tó ní ọtí. Kó má mu ohun kíkan tí wọ́n fi wáìnì ṣe tàbí ohun kíkan tí wọ́n fi nǹkan tó ní ọtí+ ṣe. Kó má mu ohunkóhun tí wọ́n fi èso àjàrà ṣe, kó má sì jẹ èso àjàrà, ì báà jẹ́ tútù tàbí gbígbẹ.

  • Lúùkù 1:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 torí ẹni ńlá ló máa jẹ́ lójú Jèhófà.*+ Àmọ́ kò gbọ́dọ̀ mu wáìnì rárá tàbí ọtí líle èyíkéyìí,+ ẹ̀mí mímọ́ sì máa kún inú rẹ̀, àní kí wọ́n tó bí i,*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́