ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 10:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 “Ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ ò gbọ́dọ̀ mu wáìnì tàbí àwọn ohun mímu míì tó ní ọtí nígbà tí ẹ bá wá sínú àgọ́ ìpàdé,+ kí ẹ má bàa kú. Àṣẹ tí ìran yín á máa pa mọ́ títí láé ni.

  • Émọ́sì 2:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Mo yan àwọn kan lára àwọn ọmọkùnrin yín láti jẹ́ wòlíì+

      Àti lára àwọn ọ̀dọ́kùnrin yín láti jẹ́ Násírì.+

      Àbí bẹ́ẹ̀ kọ́, ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì?’ ni Jèhófà wí.

      12 ‘Àmọ́, ẹ̀ ń fún Násírì ní wáìnì mu,+

      Ẹ sì ń pàṣẹ fún àwọn wòlíì pé: “Ẹ kò gbọ́dọ̀ sọ tẹ́lẹ̀.”+

  • Lúùkù 1:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 torí ẹni ńlá ló máa jẹ́ lójú Jèhófà.*+ Àmọ́ kò gbọ́dọ̀ mu wáìnì rárá tàbí ọtí líle èyíkéyìí,+ ẹ̀mí mímọ́ sì máa kún inú rẹ̀, àní kí wọ́n tó bí i,*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́