-
Jeremáyà 1:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Mo fi ọ́ ṣe wòlíì àwọn orílẹ̀-èdè.”
-
-
Róòmù 9:10-12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Kì í ṣe ìgbà yẹn nìkan, àmọ́ ó tún ṣẹlẹ̀ nígbà tí Rèbékà lóyún ìbejì fún ọkùnrin kan, ìyẹn Ísákì baba ńlá wa;+ 11 torí nígbà tí wọn ò tíì bí wọn tàbí tí wọn ò tíì ṣe rere tàbí búburú, kí ìpinnu Ọlọ́run lórí yíyàn má bàa jẹ́ nípa àwọn iṣẹ́, àmọ́ kó jẹ́ nípa Ẹni tó ń peni, 12 a sọ fún un pé: “Ẹ̀gbọ́n ni yóò jẹ́ ẹrú àbúrò.”+
-