Lúùkù 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ṣùgbọ́n áńgẹ́lì náà sọ fún un pé: “Má bẹ̀rù, Sekaráyà, torí a ti ṣojúure sí ọ, a sì ti gbọ́ ẹ̀bẹ̀ rẹ, Èlísábẹ́tì ìyàwó rẹ máa bí ọmọkùnrin kan fún ọ, kí o pe orúkọ rẹ̀ ní Jòhánù.+ Lúùkù 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 torí ẹni ńlá ló máa jẹ́ lójú Jèhófà.*+ Àmọ́ kò gbọ́dọ̀ mu wáìnì rárá tàbí ọtí líle èyíkéyìí,+ ẹ̀mí mímọ́ sì máa kún inú rẹ̀, àní kí wọ́n tó bí i,*+
13 Ṣùgbọ́n áńgẹ́lì náà sọ fún un pé: “Má bẹ̀rù, Sekaráyà, torí a ti ṣojúure sí ọ, a sì ti gbọ́ ẹ̀bẹ̀ rẹ, Èlísábẹ́tì ìyàwó rẹ máa bí ọmọkùnrin kan fún ọ, kí o pe orúkọ rẹ̀ ní Jòhánù.+
15 torí ẹni ńlá ló máa jẹ́ lójú Jèhófà.*+ Àmọ́ kò gbọ́dọ̀ mu wáìnì rárá tàbí ọtí líle èyíkéyìí,+ ẹ̀mí mímọ́ sì máa kún inú rẹ̀, àní kí wọ́n tó bí i,*+