Lúùkù 1:59, 60 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 59 Ní ọjọ́ kẹjọ, wọ́n wá láti dádọ̀dọ́* ọmọ kékeré náà,+ wọ́n sì fẹ́ sọ ọ́ ní Sekaráyà, orúkọ bàbá rẹ̀. 60 Àmọ́ ìyá rẹ̀ fèsì pé: “Rárá o! Jòhánù la máa pè é.”
59 Ní ọjọ́ kẹjọ, wọ́n wá láti dádọ̀dọ́* ọmọ kékeré náà,+ wọ́n sì fẹ́ sọ ọ́ ní Sekaráyà, orúkọ bàbá rẹ̀. 60 Àmọ́ ìyá rẹ̀ fèsì pé: “Rárá o! Jòhánù la máa pè é.”