ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 3:45
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 45 “Mú àwọn ọmọ Léfì dípò gbogbo àkọ́bí nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí o sì mú ẹran ọ̀sìn àwọn ọmọ Léfì dípò àwọn ẹran ọ̀sìn wọn, àwọn ọmọ Léfì yóò sì di tèmi. Èmi ni Jèhófà.

  • Jóṣúà 14:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Mósè ti pín ogún fún ẹ̀yà méjì àtààbọ̀ yòókù ní òdìkejì* Jọ́dánì,+ àmọ́ kò pín ogún kankan fún àwọn ọmọ Léfì láàárín wọn.+

  • Jóṣúà 18:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Àmọ́ a ò ní fún àwọn ọmọ Léfì ní ìpín kankan láàárín yín,+ torí pé iṣẹ́ àlùfáà Jèhófà ni ogún wọn;+ Gádì, Rúbẹ́nì àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè+ ti gba ogún wọn lápá ìlà oòrùn Jọ́dánì, èyí tí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà fún wọn.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́