Nọ́ńbà 18:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Áárónì lọ pé: “O ò ní ní ogún ní ilẹ̀ wọn, o ò sì ní ní ilẹ̀ kankan tó máa jẹ́ ìpín rẹ+ láàárín wọn. Èmi ni ìpín rẹ àti ogún rẹ láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ Jóṣúà 13:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Àmọ́ Mósè ò fún ẹ̀yà àwọn ọmọ Léfì ní ogún kankan.+ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ni ogún wọn, bó ṣe ṣèlérí fún wọn.+
20 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Áárónì lọ pé: “O ò ní ní ogún ní ilẹ̀ wọn, o ò sì ní ní ilẹ̀ kankan tó máa jẹ́ ìpín rẹ+ láàárín wọn. Èmi ni ìpín rẹ àti ogún rẹ láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+
33 Àmọ́ Mósè ò fún ẹ̀yà àwọn ọmọ Léfì ní ogún kankan.+ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ni ogún wọn, bó ṣe ṣèlérí fún wọn.+