ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 15:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ààlà náà dé Àfonífojì Ọmọ Hínómù,+ ó dé gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ àwọn ará Jébúsì+ ní gúúsù, ìyẹn Jerúsálẹ́mù,+ ààlà náà dé orí òkè tó dojú kọ Àfonífojì Hínómù lápá ìwọ̀ oòrùn, èyí tó wà ní ìkángun Àfonífojì* Réfáímù lápá àríwá.

  • Jóṣúà 15:63
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 63 Àmọ́ àwọn ọkùnrin Júdà kò lè lé àwọn ará Jébúsì+ tó ń gbé Jerúsálẹ́mù+ lọ,+ torí náà àwọn ará Jébúsì ṣì ń gbé pẹ̀lú àwọn èèyàn Júdà ní Jerúsálẹ́mù títí di òní yìí.

  • Jóṣúà 18:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Séélà,+ Ha-éléfì, Jẹ́búsì, ìyẹn Jerúsálẹ́mù,+ Gíbíà+ àti Kíríátì, gbogbo rẹ̀ jẹ́ ìlú mẹ́rìnlá (14), pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.

      Èyí ni ogún àwọn àtọmọdọ́mọ Bẹ́ńjámínì ní ìdílé-ìdílé.

  • Àwọn Onídàájọ́ 1:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Bákan náà, àwọn ọkùnrin Júdà bá Jerúsálẹ́mù+ jà, wọ́n sì gbà á; wọ́n fi idà pa á run, wọ́n sì dáná sun ìlú náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́