ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 18:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ààlà náà lọ dé ìkángun òkè tó dojú kọ Àfonífojì Ọmọ Hínómù,+ èyí tó wà ní Àfonífojì* Réfáímù+ lápá àríwá, ó sì lọ dé Àfonífojì Hínómù, dé gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ àwọn ará Jébúsì+ ní gúúsù, títí dé Ẹ́ń-rógélì.+

  • Jóṣúà 18:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Jọ́dánì sì ni ààlà rẹ̀ lápá ìlà oòrùn. Èyí ni ogún àwọn àtọmọdọ́mọ Bẹ́ńjámínì ní ìdílé-ìdílé, gẹ́gẹ́ bí àwọn ààlà rẹ̀ yí ká.

  • 2 Àwọn Ọba 23:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ó tún sọ Tófétì+ tó wà ní Àfonífojì Àwọn Ọmọ Hínómù*+ di ibi tí kò ṣeé lò fún ìjọsìn, kí ẹnikẹ́ni má bàa sun ọmọkùnrin rẹ̀ tàbí ọmọbìnrin rẹ̀ nínú iná sí Mólékì.+

  • Jeremáyà 7:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Wọ́n ti kọ́ àwọn ibi gíga Tófétì, èyí tó wà ní Àfonífojì Ọmọ Hínómù,*+ láti sun àwọn ọmọkùnrin wọn àti àwọn ọmọbìnrin wọn nínú iná,+ ohun tí mi ò pa láṣẹ, tí kò sì wá sí mi lọ́kàn rí.’*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́