ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 23:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 ohun ìní Ábúráhámù, èyí tó rà níṣojú àwọn ọmọ Hétì àti gbogbo àwọn tó ń gba ẹnubodè ìlú rẹ̀ wọlé.

  • Jeremáyà 32:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Nítorí náà, mo ra ilẹ̀ tó wà ní Ánátótì lọ́wọ́ Hánámélì ọmọ arákùnrin bàbá mi. Mo sì wọn owó+ fún un, ṣékélì* méje àti ẹyọ fàdákà mẹ́wàá. 10 Lẹ́yìn náà, mo ṣe ìwé àdéhùn,+ mo sì gbé èdìdì lé e, mo pe àwọn ẹlẹ́rìí wá,+ mo sì wọn owó náà lórí òṣùwọ̀n.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́