ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 32:44
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 44 “‘Àwọn èèyàn á fi owó ra ilẹ̀, wọ́n á ṣe ìwé àdéhùn tí wọ́n fi rà á, wọ́n á gbé èdìdì lé e, wọ́n á sì pe àwọn ẹlẹ́rìí ní ilẹ̀ Bẹ́ńjámínì,+ ní agbègbè Jerúsálẹ́mù àti ní àwọn ìlú Júdà,+ ní àwọn ìlú tó wà ní àwọn agbègbè olókè àti ní àwọn ìlú tó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀+ pẹ̀lú àwọn ìlú tó wà ní gúúsù, torí pé màá mú àwọn èèyàn wọn tó wà lóko ẹrú pa dà wá,’+ ni Jèhófà wí.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́